- Ṣiṣenilojukokoro lori ikọṣe Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – nibi iwuwasi rẹ pẹlu awọn iwa Alukurāni.
- Yiyin awọn iwa ojiṣẹ Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – ati pe ninu òpó àtùpà imisi l’o ti wa.
- Alukurāni ipilẹ l’o jẹ fun gbogbo awọn iwa alapọn-ọnle.
- Awọn iwa ninu Isilāmu ko gbogbo ẹsin sinu pẹlu ṣiṣe awọn aṣẹ ati jijina sí awọn eewọ.