- O di dandan fun onigbagbọ ododo ki o jìnnà si ọ̀rọ̀ burúkú àti ìṣe burúkú.
- Pipe iwa ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- kii wa lati ọdọ rẹ ayafi iṣẹ rere ati ọ̀rọ̀ rere.
- Ìwà rere jẹ pápá ìṣeré fun ìdíje, ẹni tí ó bá gba iwájú maa wa ninu awọn onigbagbọ òdodo ti wọn loore ju ti igbagbọ wọn si pe ju.