Dajudaju Ojiṣẹ Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – kọ nkan ti n jẹ al-Qaza‘ (ki èèyàn fá orí apakan ki o dá apakan sí)
Lati ọdọ ọmọ ‘Umar – ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji -: Dajudaju Ojiṣẹ Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – kọ nkan ti n jẹ al-Qaza‘ (ki èèyàn fá orí apakan ki o dá apakan sí).
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
Àlàyé
Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – kọ fifa apakan irun ori ati fifi apakan silẹ.
Ati pe kikọ naa ko gbogbo ọmọde ọkunrin ati agbalagba ọkunrin sinu, ṣugbọn ọmọbinrin ko tọ fun un ki o fa irun ori rẹ.
Hadeeth benefits
Nini akolekan ofin Isilāmu si irisi ọmọnìyàn.
Share
Use the QR code to easily share the message of Islam with others