- Ìní ẹtọ ìgbádùn àwọn nǹkan ti o dáa ni ayé, eyi ti Ọlọhun ṣe ni ẹtọ fun awọn ẹru Rẹ láìsí ìná-àpà tabi ìgbéraga.
- Ṣiṣenilojukokoro lori yíyan ìyàwó rere; tori pe iranlọwọ ni in fun ọkọ lati tẹle àṣẹ Olúwa rẹ.
- Eyi ti o loore julọ ninu ìgbádùn ayé ni eyi ti o ba wa fun itẹle àṣẹ Ọlọhun, tabi ti o ṣe iranlọwọ lati tẹle àṣẹ Ọlọhun.