- Jijẹ dandan mimu awọn majẹmu ṣẹ ti ọkan ninu ọkọ ati iyawo ṣe ni dandan fun ara wọn, afi majẹmu kan ti o ṣe ẹtọ ni eewọ tabi ṣe eewọ lẹtọọ.
- Mimu awọn majẹmu yigi ṣẹ jẹ nnkan ti o kanpa ju nnkan ti o yatọ si wọn lọ; nitori pe o jẹ ìjìrọ̀ fun sisọ awọn abẹ di ẹtọ.
- Titobi ipo igbeyawo ninu Isilaamu, latari bi o ṣe kanpá mọ́ mimu awọn majẹmu rẹ ṣẹ.