- Ṣíṣe odì ni ẹtọ fun ọjọ mẹta tabi ki o ma to bẹẹ, fun ti adamọ ti ọmọniyan, wọn wa yọnda odì fun ọjọ mẹta ki nǹkan ti o ṣẹri wa yẹn le lọ.
- Ọla ti n bẹ fun salamọ, ati pe o maa mu ohun ti n bẹ ninu ẹmi kúrò, o si tun jẹ àmì fun ìfẹ́.
- Ojúkòkòrò Isilaamu lori ijẹ ọmọ-iya ati ifẹ láàrin àwọn Musulumi.