- Ikilọ ti o le kuro nibi ki Musulumi o ba awọn ọmọ-iya rẹ Musulumi ja.
- Ninu awọn ibajẹ ti o tobi julọ ni orilẹ ni yiyọ nkan ija si awọn Musulumi, ati ṣiṣe ibajẹ pẹlu ipaniyan.
- Adehun iya ti wọn sọ yẹn ko ko ìjà pẹlu ẹtọ sinu, gẹgẹ bii biba awọn olutayọ ala ati awọn aṣebajẹ ati awọn ti o yatọ si wọn ja.
- Ṣiṣe idẹruba awọn Musulumi pẹlu nkan ija tabi eyi ti o yatọ si i ni eewọ– koda ki o jẹ ni ọna awada -.