- Aba dida burúkú ko ki n ko inira ba ẹni ti awọn ami rẹ ba han lara rẹ, o wa jẹ dandan fun olugbagbọ lati jẹ ẹni ti o gbọn ninu ati lẹyin ti ko nii gba ẹtanjẹ pẹlu awọn ẹni buruku ati awọn pooki.
- Nǹkan ti a gba lero ni ikilọ kúrò nibi kikẹfin ti o maa n rinlẹ ninu ẹmi, ati titaku lori rẹ, sugbọn eyi ti o maa n ṣẹlẹ̀ ninu ẹmi ti ko rinlẹ, eleyii wọn ko la a bọ ọ lọrun.
- Ṣíṣe awọn okunfa ìkórìíra-ara-ẹni ati opinya laaarin ẹni kọọkan ninu àwùjọ Musulumi leewọ, bii itọpinpin ati keeta ati nnkan ti o jọ mejeeji.
- Asọtẹlẹ pẹlu biba Musulumi lo ni ibalo ọmọ iya nibi igbani ni ìmọ̀ràn ati ini ifẹ ara ẹni.