- Titobi àlámọ̀rí awọn ẹjẹ, nitori pe ìbẹ̀rẹ̀ maa n jẹ pẹlu eyi ti o ṣe pataki julọ.
- Awọn ẹṣẹ maa tobi ni ibamu si titobi ibajẹ ti o wa nibẹ, ati ita awọn ẹmi alaiṣẹ silẹ wa ninu eyi ti o tobi julọ ninu ibajẹ, ko si eyi ti o tobi ju u lọ afi ṣíṣe aigbagbọ ati dida orogun pọ mọ Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga-.