- Ìní akolekan si titun ọkàn ṣe, ati mimọ ọn kuro nibi gbogbo ìròyìn burúkú.
- Dídára ọkàn pẹ̀lú imọkanga ni, dídára iṣẹ pẹ̀lú itẹle Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ni, àwọn méjèèjì yii ni Ọlọhun maa wò.
- Ọmọniyan ko gbọdọ gba ẹtan pẹ̀lú dúkìá rẹ tabi ẹwà rẹ tabi ara rẹ, tabi nǹkan kan ninu àwòrán ayé yii.
- Ikilọ kuro nibi ifayabalẹ lori ìta ti o hàn lai tún inú ti o pamọ ṣe.